Jẹnẹsisi 24:10 BM

10 Iranṣẹ náà mú mẹ́wàá ninu àwọn ràkúnmí oluwa rẹ̀, ó gba oríṣìíríṣìí ẹ̀bùn àtàtà lọ́wọ́ oluwa rẹ̀, ó jáde lọ sí ilẹ̀ Mesopotamia, sí ìlú Nahori.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:10 ni o tọ