9 Iranṣẹ náà bá ti ọwọ́ rẹ̀ bọ abẹ́ itan Abrahamu oluwa rẹ̀, ó sì búra láti ṣe ohun tí Abrahamu pa láṣẹ fún un.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24
Wo Jẹnẹsisi 24:9 ni o tọ