Jẹnẹsisi 24:8 BM

8 Ṣugbọn bí obinrin náà bá kọ̀ tí kò tẹ̀lé ọ, nígbà náà ọrùn rẹ yóo mọ́ ninu ìbúra tí o búra fún mi, ṣá má ti mú ọmọ mi pada sibẹ.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:8 ni o tọ