Jẹnẹsisi 24:36 BM

36 Sara, aya oluwa mi bí ọmọkunrin kan fún un lẹ́yìn tí ó ti di arúgbó, ọmọ yìí sì ni oluwa mi fi ohun gbogbo tí ó ní fún.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:36 ni o tọ