Jẹnẹsisi 24:37 BM

37 Oluwa mi mú mi búra pé n kò gbọdọ̀ fẹ́ aya fún ọmọ òun láàrin àwọn ará ilẹ̀ Kenaani tí òun ń gbé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:37 ni o tọ