60 Wọ́n súre fún Rebeka, wọ́n wí pé, “Arabinrin wa, o óo bírún, o óo bígba. Àwọn ọmọ rẹ yóo máa borí àwọn ọ̀tá wọn.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24
Wo Jẹnẹsisi 24:60 ni o tọ