Jẹnẹsisi 24:61 BM

61 Rebeka ati àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀ bá gun ràkúnmí, wọ́n tẹ̀lé ọkunrin náà. Bẹ́ẹ̀ ni iranṣẹ náà ṣe mú Rebeka lọ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:61 ni o tọ