Jẹnẹsisi 24:65 BM

65 Ó bi iranṣẹ Abrahamu náà pé, “Ta ni ó ń rìn ninu pápá lọ́ọ̀ọ́kán tí ó ń bọ̀ wá pàdé wa yìí?” Iranṣẹ náà dá a lóhùn pé, “Olúwa mi ni.” Rebeka bá mú ìbòjú rẹ̀, ó dà á bojú.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:65 ni o tọ