Jẹnẹsisi 24:66 BM

66 Nígbà tí wọ́n pàdé Isaaki, iranṣẹ náà ròyìn gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 24

Wo Jẹnẹsisi 24:66 ni o tọ