17 Iye ọdún tí Iṣimaeli gbé láyé jẹ́ ọdún mẹtadinlogoje (137). Nígbà tí ó kú a sin ín pẹlu àwọn eniyan rẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25
Wo Jẹnẹsisi 25:17 ni o tọ