Jẹnẹsisi 25:18 BM

18 Àwọn ọmọ Iṣimaeli sì ń gbé ilẹ̀ tí ó bẹ̀rẹ̀ láti Hafila títí dé Ṣuri, tí ó wà ní òdìkejì Ijipti, ní apá Asiria. Wọ́n tẹ̀dó sí òdìkejì àwọn eniyan wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 25

Wo Jẹnẹsisi 25:18 ni o tọ