Jẹnẹsisi 26:10 BM

10 Abimeleki bá dá a lóhùn pé, “Irú kí ni o dánwò sí wa yìí? Ǹjẹ́ bí ọ̀kan ninu àwọn eniyan wọnyi bá ti bá aya rẹ lòpọ̀ ńkọ́? O ò bá mú ẹ̀bi wá sórí wa.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26

Wo Jẹnẹsisi 26:10 ni o tọ