Jẹnẹsisi 26:11 BM

11 Nítorí náà Abimeleki kìlọ̀ fún gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ọwọ́ kan ọkunrin yìí tabi aya rẹ̀, pípa ni wọn yóo pa á.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26

Wo Jẹnẹsisi 26:11 ni o tọ