Jẹnẹsisi 26:3 BM

3 Ọlọrun ní, “Máa gbé ilẹ̀ yìí, n óo wà pẹlu rẹ, n óo sì bukun ọ, nítorí ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ ni n óo fún ní ilẹ̀ wọnyi, n óo sì mú ìlérí mi fún Abrahamu, baba rẹ ṣẹ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26

Wo Jẹnẹsisi 26:3 ni o tọ