Jẹnẹsisi 26:4 BM

4 N óo sọ àwọn ọmọ rẹ di pupọ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, n óo sì fún wọn ní ilẹ̀ wọnyi. Nípasẹ̀ wọn ni n óo bukun gbogbo orílẹ̀-èdè ayé,

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 26

Wo Jẹnẹsisi 26:4 ni o tọ