30 Bí Isaaki ti súre fún Jakọbu tán, Jakọbu fẹ́rẹ̀ má tíì jáde kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ tí Esau ẹ̀gbọ́n rẹ̀ fi ti oko ọdẹ dé.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27
Wo Jẹnẹsisi 27:30 ni o tọ