Jẹnẹsisi 27:31 BM

31 Òun náà se oúnjẹ aládùn, ó gbé e tọ baba rẹ̀ wá, ó wí fún un pé, “Baba mi, dìde, kí o jẹ ninu ẹran tí èmi ọmọ rẹ pa, kí o lè súre fún mi.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27

Wo Jẹnẹsisi 27:31 ni o tọ