34 Nígbà tí Esau gbọ́ ohun tí baba rẹ̀ sọ, ó fi igbe ta, ó sọkún kíkorò, ó wí pé, “Baba mi, súre fún èmi náà.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 27
Wo Jẹnẹsisi 27:34 ni o tọ