Jẹnẹsisi 28:2 BM

2 Ó ní, “Dìde, lọ sí ilé Betueli, baba ìyá rẹ, ní Padani-aramu, kí o sì fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Labani, arakunrin ìyá rẹ.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:2 ni o tọ