Jẹnẹsisi 28:3 BM

3 Ọlọrun Olodumare yóo bukun ọ, yóo fún ọ ní ọmọ pupọ, yóo sì sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:3 ni o tọ