Jẹnẹsisi 28:9 BM

9 Nítorí náà Esau lọ sọ́dọ̀ Iṣimaeli ọmọ Abrahamu, ó sì fẹ́ Mahalati ọmọ rẹ̀, tíí ṣe arabinrin Nebaiotu, ó fi kún àwọn aya tí ó ti ní.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 28

Wo Jẹnẹsisi 28:9 ni o tọ