Jẹnẹsisi 29:10 BM

10 Nígbà tí Jakọbu rí Rakẹli, ọmọ Labani, tíí ṣe arakunrin ìyá rẹ̀, ati agbo aguntan Labani, ó yí òkúta náà kúrò lẹ́nu kànga, ó sì pọn omi fún wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:10 ni o tọ