9 Bí ó ti ń bá wọn sọ̀rọ̀ lọ́wọ́ ni Rakẹli dé pẹlu agbo aguntan baba rẹ̀, nítorí pé òun ni ó ń tọ́jú wọn.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29
Wo Jẹnẹsisi 29:9 ni o tọ