Jẹnẹsisi 29:8 BM

8 Wọ́n dá a lóhùn pé, “Kò ṣeéṣe, àfi bí gbogbo àwọn olùṣọ́-aguntan bá dé tán, tí a bá yí òkúta kúrò lórí kànga, nígbà náà ni a tó lè fún àwọn aguntan ní omi mu.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:8 ni o tọ