Jẹnẹsisi 29:7 BM

7 Jakọbu sọ pé, “Oòrùn ṣì wà lókè, kò tíì tó àkókò láti kó àwọn ẹran jọ sójú kan, ẹ tètè fún àwọn aguntan ní omi mu, kí ẹ sì dà wọ́n pada lọ jẹ koríko sí i.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:7 ni o tọ