32 Lea lóyún, ó bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọ́ ní Reubẹni, ó ní, “Nítorí OLUWA ti ṣíjú wo ìpọ́njú mi; nisinsinyii, ọkọ mi yóo fẹ́ràn mi.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29
Wo Jẹnẹsisi 29:32 ni o tọ