33 Ó tún lóyún, ó tún bí ọkunrin, ó ní, “Nítorí pé OLUWA ti gbọ́ pé wọ́n kórìíra mi ni ó ṣe fún mi ní ọmọ yìí pẹlu.” Ó bá sọ ọ́ ní Simeoni.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29
Wo Jẹnẹsisi 29:33 ni o tọ