Jẹnẹsisi 29:34 BM

34 Ó tún lóyún, ó sì tún bí ọkunrin, ó ní, “Ọkọ mi gbọdọ̀ faramọ́ mi wàyí, nítorí pé ó di ọkunrin mẹta tí mo bí fún un”, nítorí náà, ó sọ ọmọ náà ní Lefi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29

Wo Jẹnẹsisi 29:34 ni o tọ