35 Ó tún lóyún ó sì tún bí ọkunrin, ó ní, “Wàyí o, n óo yin OLUWA,” ó bá sọ ọ́ ní Juda. Lẹ́yìn rẹ̀, kò bímọ mọ́.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 29
Wo Jẹnẹsisi 29:35 ni o tọ