Jẹnẹsisi 3:23 BM

23 Nítorí náà OLUWA Ọlọrun lé e jáde kúrò ninu ọgbà Edẹni, kí ó lọ máa ro ilẹ̀, ninu èyí tí Ọlọrun ti mú un jáde.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 3

Wo Jẹnẹsisi 3:23 ni o tọ