Jẹnẹsisi 3:24 BM

24 Ó lé e jáde, ó sì fi Kerubu kan sí ìhà ìlà oòrùn ọgbà náà láti máa ṣọ́ ọ̀nà tí ó lọ sí ibi igi ìyè náà, pẹlu idà oníná tí ń jò bùlà bùlà, tí ó sì ń yí síhìn-ín sọ́hùn-ún.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 3

Wo Jẹnẹsisi 3:24 ni o tọ