Jẹnẹsisi 30:6 BM

6 Rakẹli bá sọ pé, “Ọlọrun dá mi láre, ó gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi, ó sì fún mi ní ọmọkunrin kan.” Nítorí náà, ó sọ ọmọ náà ní Dani.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30

Wo Jẹnẹsisi 30:6 ni o tọ