7 Biliha, iranṣẹbinrin Rakẹli tún lóyún, ó bí ọmọkunrin keji fún Jakọbu.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 30
Wo Jẹnẹsisi 30:7 ni o tọ