Jẹnẹsisi 31:48 BM

48 Labani wí pé, “Òkítì yìí ni ohun ẹ̀rí láàrin èmi pẹlu rẹ lónìí.” Nítorí náà ó sọ ọ́ ní Galeedi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:48 ni o tọ