Jẹnẹsisi 31:49 BM

49 Ó sì sọ ọ̀wọ̀n náà ní Misipa, nítorí ó wí pé, “Kí OLUWA ṣọ́ wa nígbà tí a bá pínyà lọ́dọ̀ ara wa.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:49 ni o tọ