Jẹnẹsisi 31:53 BM

53 Ọlọrun Abrahamu ati Ọlọrun Nahori, àní, Ọlọrun baba wọn ni onídàájọ́ láàrin wa.” Jakọbu náà bá búra ní orúkọ Ọlọrun tí Isaaki baba rẹ̀ ń sìn tìbẹ̀rùtìbẹ̀rù.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:53 ni o tọ