Jẹnẹsisi 31:54 BM

54 Jakọbu bá rúbọ lórí òkè náà, ó pe àwọn ìbátan rẹ̀ láti jẹun, wọ́n sì wà lórí òkè náà ní gbogbo òru ọjọ́ náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:54 ni o tọ