Jẹnẹsisi 31:55 BM

55 Ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, Labani fi ẹnu ko àwọn ọmọbinrin rẹ̀ ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ lẹ́nu láti dágbére fún wọn, ó súre fún wọn, ó sì pada sílé.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 31

Wo Jẹnẹsisi 31:55 ni o tọ