Jẹnẹsisi 32:6 BM

6 Nígbà tí àwọn oníṣẹ́ náà pada wá jábọ̀ fún Jakọbu, wọ́n sọ fún un pé, “A jíṣẹ́ rẹ fún Esau arakunrin rẹ, ó sì ń bọ̀ wá pàdé rẹ pẹlu irinwo (400) ọkunrin.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:6 ni o tọ