Jẹnẹsisi 32:7 BM

7 Ẹ̀rù ba Jakọbu gidigidi, ó sì dààmú, ó bá dá àwọn eniyan tí wọn wà pẹlu rẹ̀ ati agbo mààlúù, ati agbo aguntan ati àwọn ràkúnmí rẹ̀ sí ọ̀nà meji meji.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 32

Wo Jẹnẹsisi 32:7 ni o tọ