Jẹnẹsisi 35:6 BM

6 Jakọbu ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ bá wá sí Lusi, tí ó wà ní ilẹ̀ Kenaani, èyí nnì ni Bẹtẹli.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:6 ni o tọ