Jẹnẹsisi 35:7 BM

7 Ó tẹ́ pẹpẹ kan sibẹ, ó sì sọ ibẹ̀ ní Eli-Bẹtẹli, nítorí pé níbẹ̀ ni Ọlọrun ti farahàn án nígbà tí ó ń sálọ fún arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 35

Wo Jẹnẹsisi 35:7 ni o tọ