Jẹnẹsisi 37:3 BM

3 Israẹli fẹ́ràn Josẹfu ju gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ yòókù lọ, nítorí pé ó ti di arúgbó kí ó tó bí i, nítorí náà ó dá ẹ̀wù aláràbarà kan fún un.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:3 ni o tọ