Jẹnẹsisi 37:4 BM

4 Nígbà tí àwọn arakunrin rẹ̀ yòókù rí i pé baba wọn fẹ́ràn Josẹfu ju àwọn lọ, wọ́n kórìíra rẹ̀, wọn kì í sì fi sùúrù bá a sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:4 ni o tọ