32 Wọ́n bá fi ẹ̀wù aláràbarà náà ranṣẹ sí baba wọn, wọ́n ní, “Ohun tí a rí nìyí. Wò ó wò, bóyá ẹ̀wù ọmọ rẹ ni, tabi òun kọ́.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37
Wo Jẹnẹsisi 37:32 ni o tọ