33 Jakọbu yẹ̀ ẹ́ wò, ó sì wí pé, “Ẹ̀wù ọmọ mi ni, ẹranko burúkú kan ti pa á, dájúdájú, ẹranko náà ti fa Josẹfu ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37
Wo Jẹnẹsisi 37:33 ni o tọ