Jẹnẹsisi 37:36 BM

36 Àwọn ará Midiani tí wọ́n ra Josẹfu tà á fún Pọtifari, ará Ijipti, ọ̀kan ninu àwọn ìjòyè Farao. Pọtifari yìí ni olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ọba.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 37

Wo Jẹnẹsisi 37:36 ni o tọ