Jẹnẹsisi 38:1 BM

1 Kò pẹ́ pupọ lẹ́yìn náà ni Juda bá fi àwọn arakunrin rẹ̀ sílẹ̀, ó kó lọ sí ọ̀dọ̀ ará Adulamu kan tí wọn ń pè ní Hira.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 38

Wo Jẹnẹsisi 38:1 ni o tọ