Jẹnẹsisi 39:1 BM

1 Àwọn ará Iṣimaeli mú Josẹfu lọ sí Ijipti, wọ́n sì tà á fún Pọtifari ará Ijipti. Pọtifari yìí jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ìjòyè Farao, òun sì tún ni olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ọba.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:1 ni o tọ