Jẹnẹsisi 39:2 BM

2 OLUWA wà pẹlu Josẹfu, ninu ilé ọ̀gá rẹ̀, ará Ijipti, níbi tí ó ń gbé. Àwọn ohun tí ó ń ṣe sì ń yọrí sí rere.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 39

Wo Jẹnẹsisi 39:2 ni o tọ